IYE
Won ni kasora fun oda
Sugbon igba ti ikilo yen wa
Eru n be nile
Nio je ki a robi rore
Won ni ki a se kini, a se
Won ni ki ara nkan ile yi
Ka gbe feni bayi
Gbogbo re pata lase
Asiko ti wa to
Abi ki la n ri
Egberun ogun ti tan
Ogorun ogbon ti wole
B'ase wa na iye, iyen ni kowa ye
A ti wa lo ati de
Araabi ti tan
Oun ti awi tari
Otun wa n losi ni, iyen gan ko tun ye
Ati wa pe ile
Ibi ta ti wa, ibi tawi lawi
Se bi iku ile ba danisi
Tode ko le pani
Je ki awa gbo oun ti won fe wi
Awon akilo ire ati ibi
Bi iku ile ba de, ti n ba rori ye
Ajo ti daju
Mo ti de, mo ti de
Olorun loke baba gbani gbani
Fi han awon ti o ran
Nkan gangan tode
Ti iye ko fi yeni mo
AMOUNT
They warned against draught
But when that warning came
There was a load on ground
So we didn't think evil to good
They asked us to do something, we did
They told us to buy something of this land
And give it to someone (described)
We did every thing
Now it is time
Or what are we seeing
Thousands (of twenties) have finished
Hundreds (of thirties) have vanished
How we then spent the amount is the thing we don't understand
We went and we are back
This thing was exhausted
What we said and saw
It's even going the more, that one too we don't understand
We have called home
Where we came from, where we said
If death spares you at home
It is difficult to die outside
Let us now listen to what they have to say
The warners of good and evil
When we are able to escape the home death
The journey is sure
Here I am, here I am
God in heaven, Father, the saviour
Show those you sent
What exactly went wrong
Why we don't get the amount again
DAUDA ONAWOLA
IG: @d.phinix
@onawolaDAUDA
No comments:
Post a Comment